ÀGBÉYỆWÒ ỌDÚN ORÒ ALÁÚȘỆ NÍ ÌLÚ ÌRÙN ÀKÓKÓ
Abstract
Isé ìwádií yìí kò ni kún tó bí mo bá se àgbéyèwò tí ó jọjú tí mo sì kíyèsí àwọn hyípudi ti ó tí bá ọdún náà láifǐ ìmọràn tè mi síì.
Orin ọdún Orò Aláúșệ tí ó ń șeré làáárín ìlú àti àwọn ọmọ ilé-ìwé ti ń gba ipò rè ń féàmójú tó. Yóo dára tía bá le fi ipìnlệ ijìnlè orin Aláúșè le àwọn ti o sèsè n bọ lówó ki wọn le mọ àwọn kókó tí ó ń súyọ nínú orin Aláúse.
Lónà keji, ó yẹ kí àwọn ọmọ àdúgbò yìí máa gbìyànjú láti máa kópa nínú ọdún Aláúșèju kí wón jé ònwòran lọ, Șé bí onwòran dbí ti pộ ju akópa lọ, ọdún kò le dún mó, yóò dára bía bá ni èmí isìn.Lákòótán ó sọrọ láti sọ pé ọdún Orò Aláúșè yóo paré. Șé bí òní ti ri òla kò rí béè ni babalawo fi n dífá ộrọòrun, a lè sọ pé yóò paré kí ìgbàgbé dé bá ọdún Orò Aláúsè yìí, láti ọwó àwọn akópa rè. Ju gbogbo rè lọ, èmi ìfé ti a bá fìhan sódún yìí ni yóò fa èmí gígun rè.Bákan náà, bí àwọn ọdún ibílè Yorùbá yóòkư kò bà ti parè, kokoko làá máa gbó nílé aróọdún Orò Aláúșè ilú Ìrun-Àkókó.
Full-Text Access Notice
In accordance with the NERD Policy on promoting peer-reviewed publication, public access to the full text of a project, thesis or dissertation is restricted for three years, allowing the author and supervisors sufficient time to pursue peer-reviewed publication.
During this period, researchers with legitimate academic or research purposes may request authorisation directly from the author to enable NERD to release the indexed full texts of the work using the form below.